-
Jóòbù 12:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ó ń pa àwọn agbani-nímọ̀ràn tí wọ́n fọkàn tán lẹ́nu mọ́,
Ó sì ń gba làákàyè àwọn àgbà ọkùnrin;*
-
Àìsáyà 19:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Wọ́n máa yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí,
Àwọn atujú, àwọn abẹ́mìílò àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́.+
-
-
-