Àìsáyà 19:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Òmùgọ̀ ni àwọn olórí Sóánì.+ Ìmọ̀ràn tí kò bọ́gbọ́n mu làwọn tó gbọ́n jù nínú àwọn agbani-nímọ̀ràn Fáráò ń mú wá.+ Báwo lẹ ṣe máa sọ fún Fáráò pé: “Àtọmọdọ́mọ àwọn ọlọ́gbọ́n ni mí,Àtọmọdọ́mọ àwọn ọba àtijọ́”? Àìsáyà 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn olórí Sóánì ti hùwà òpònú;Wọ́n ti tan àwọn olórí Nófì*+ jẹ;Àwọn ìjòyè àwọn ẹ̀ya rẹ̀ ti kó Íjíbítì ṣìnà.
11 Òmùgọ̀ ni àwọn olórí Sóánì.+ Ìmọ̀ràn tí kò bọ́gbọ́n mu làwọn tó gbọ́n jù nínú àwọn agbani-nímọ̀ràn Fáráò ń mú wá.+ Báwo lẹ ṣe máa sọ fún Fáráò pé: “Àtọmọdọ́mọ àwọn ọlọ́gbọ́n ni mí,Àtọmọdọ́mọ àwọn ọba àtijọ́”?
13 Àwọn olórí Sóánì ti hùwà òpònú;Wọ́n ti tan àwọn olórí Nófì*+ jẹ;Àwọn ìjòyè àwọn ẹ̀ya rẹ̀ ti kó Íjíbítì ṣìnà.