Diutarónómì 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀. Sáàmù 115:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà ń rántí wa, á sì bù kún wa;Á bù kún ilé Ísírẹ́lì;+Á bù kún ilé Áárónì. Àìsáyà 61:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n máa mọ àwọn ọmọ* wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè +Àti àtọmọdọ́mọ wọn láàárín àwọn èèyàn. Gbogbo àwọn tó bá rí wọn máa dá wọn mọ̀,Pé àwọn ni ọmọ* tí Jèhófà bù kún.”+
9 Wọ́n máa mọ àwọn ọmọ* wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè +Àti àtọmọdọ́mọ wọn láàárín àwọn èèyàn. Gbogbo àwọn tó bá rí wọn máa dá wọn mọ̀,Pé àwọn ni ọmọ* tí Jèhófà bù kún.”+