1 Àwọn Ọba 8:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 “Tí wọ́n bá ṣẹ̀ ọ́ (nítorí kò sí èèyàn tí kì í dẹ́ṣẹ̀),+ tí inú rẹ ru sí wọn, tí o fi wọ́n sílẹ̀ fún ọ̀tá, tí àwọn tó mú wọn sì kó wọn lẹ́rú lọ si ilẹ̀ ọ̀tá, bóyá èyí tó jìnnà tàbí èyí tó wà nítòsí;+
46 “Tí wọ́n bá ṣẹ̀ ọ́ (nítorí kò sí èèyàn tí kì í dẹ́ṣẹ̀),+ tí inú rẹ ru sí wọn, tí o fi wọ́n sílẹ̀ fún ọ̀tá, tí àwọn tó mú wọn sì kó wọn lẹ́rú lọ si ilẹ̀ ọ̀tá, bóyá èyí tó jìnnà tàbí èyí tó wà nítòsí;+