- 
	                        
            
            Àìsáyà 3:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Wò ó! Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ó ń mú gbogbo ìtìlẹ́yìn àtàwọn ohun tí wọ́n nílò ní Jerúsálẹ́mù àti Júdà kúrò, Gbogbo ìtìlẹ́yìn oúnjẹ àti omi,+ - 
	                        
            
            Ìdárò 4:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Àwọn tí idà pa sàn ju àwọn tí ìyàn pa,+ Àwọn tó ń kú lọ, tí ìyàn mú débi pé ìrora wọn dà bí ìgbà tí idà gúnni. 
 
- 
                                        
 
- 
	                        
            
            
 
-