-
Jeremáyà 52:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Níkẹyìn, wọ́n fọ́ ògiri ìlú náà wọlé, gbogbo ọmọ ogun sì sá kúrò ní ìlú lóru, wọ́n gba ẹnubodè tó wà láàárín ògiri oníbejì nítòsí ọgbà ọba jáde kúrò nínú ìlú náà, lákòókò yìí, àwọn ará Kálídíà yí ìlú náà ká; wọ́n gba ọ̀nà Árábà lọ.+
-