Jẹ́nẹ́sísì 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì,+ Mágọ́gù,+ Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+ Jẹ́nẹ́sísì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọmọ Jáfánì ni Élíṣáhì,+ Táṣíṣì,+ Kítímù+ àti Dódánímù. Jeremáyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 ‘Ṣùgbọ́n ẹ kọjá sí etíkun* àwọn ará Kítímù+ kí ẹ sì wò ó. Bẹ́ẹ̀ ni, ẹ ránṣẹ́ lọ sí Kídárì,+ kí ẹ sì fara balẹ̀ wò ó;Kí ẹ sì wò ó bóyá ohun tó dà bí èyí ti ṣẹlẹ̀ rí. Ìsíkíẹ́lì 27:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn igi ràgàjì* ti Báṣánì ni wọ́n fi ṣe àwọn àjẹ̀ rẹ,Igi sípírẹ́sì tí wọ́n fi eyín erin tẹ́ inú rẹ̀ láti àwọn erékùṣù Kítímù+ ni wọ́n fi ṣe iwájú ọkọ̀ rẹ.
10 ‘Ṣùgbọ́n ẹ kọjá sí etíkun* àwọn ará Kítímù+ kí ẹ sì wò ó. Bẹ́ẹ̀ ni, ẹ ránṣẹ́ lọ sí Kídárì,+ kí ẹ sì fara balẹ̀ wò ó;Kí ẹ sì wò ó bóyá ohun tó dà bí èyí ti ṣẹlẹ̀ rí.
6 Àwọn igi ràgàjì* ti Báṣánì ni wọ́n fi ṣe àwọn àjẹ̀ rẹ,Igi sípírẹ́sì tí wọ́n fi eyín erin tẹ́ inú rẹ̀ láti àwọn erékùṣù Kítímù+ ni wọ́n fi ṣe iwájú ọkọ̀ rẹ.