ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 27:32, 33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Bí wọ́n bá ń dárò, wọn yóò máa kọrin arò nípa rẹ pé:

      ‘Ta ló dà bíi Tírè, tó ti dákẹ́ sínú òkun?+

      33 Nígbà tí àwọn ọjà rẹ ti òkun dé, o tẹ́ ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́rùn.+

      Ọrọ̀ rẹ tó pọ̀ rẹpẹtẹ àti àwọn ọjà rẹ ti sọ àwọn ọba ayé di ọlọ́rọ̀.+

  • Ìsíkíẹ́lì 28:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 O ti fi ọgbọ́n àti òye rẹ sọ ara rẹ di ọlọ́rọ̀,

      O sì ń kó wúrà àti fàdákà jọ síbi ìṣúra rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́