Àìsáyà 60:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+
5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+