Jeremáyà 4:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nítorí èyí, ilẹ̀ náà máa ṣọ̀fọ̀,+Àwọn ọ̀run á sì ṣókùnkùn.+ Torí pé mo ti sọ̀rọ̀, mo sì ti pinnu,Mi ò ní pèrò dà,* bẹ́ẹ̀ sì ni mi ò ní yí pa dà.+ Ìdárò 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá.
28 Nítorí èyí, ilẹ̀ náà máa ṣọ̀fọ̀,+Àwọn ọ̀run á sì ṣókùnkùn.+ Torí pé mo ti sọ̀rọ̀, mo sì ti pinnu,Mi ò ní pèrò dà,* bẹ́ẹ̀ sì ni mi ò ní yí pa dà.+
4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá.