-
Jeremáyà 8:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 ‘Nígbà tí mo bá kó wọn jọ, màá pa wọ́n run,’ ni Jèhófà wí.
‘Kò ní sí èso tó máa ṣẹ́ kù lórí igi àjàrà, bẹ́ẹ̀ ni kò ní sí èso kankan lórí igi ọ̀pọ̀tọ́, àwọn ewé rẹ̀ yóò sì rọ.
Wọ́n á pàdánù àwọn ohun tí mo fún wọn.’”
-