Sáàmù 132:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Jèhófà ti yan Síónì;+Ó fẹ́ kó jẹ́ ibùgbé rẹ̀, ó ní:+ Àìsáyà 12:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ké jáde, kí o sì kígbe ayọ̀, ìwọ* tó ń gbé ní Síónì,Torí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì tóbi láàárín rẹ.” Jóẹ́lì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ ó sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, tó ń gbé ní Síónì, òkè mímọ́ mi.+ Jerúsálẹ́mù yóò di ibi mímọ́,+Àwọn àjèjì* kò sì ní gbà á kọjá mọ́.+ Míkà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Èmi yóò mú kí ẹni* tó ń tiro ṣẹ́ kù,+Èmi yóò sì sọ ẹni tí wọ́n ti mú lọ sí ọ̀nà tó jìn di orílẹ̀-èdè alágbára;+Jèhófà yóò sì jọba lé wọn lórí ní Òkè Síónì,Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Sekaráyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Kígbe ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì;+ torí mò ń bọ̀,+ èmi yóò sì máa gbé láàárín rẹ,”+ ni Jèhófà wí.
17 Ẹ ó sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, tó ń gbé ní Síónì, òkè mímọ́ mi.+ Jerúsálẹ́mù yóò di ibi mímọ́,+Àwọn àjèjì* kò sì ní gbà á kọjá mọ́.+
7 Èmi yóò mú kí ẹni* tó ń tiro ṣẹ́ kù,+Èmi yóò sì sọ ẹni tí wọ́n ti mú lọ sí ọ̀nà tó jìn di orílẹ̀-èdè alágbára;+Jèhófà yóò sì jọba lé wọn lórí ní Òkè Síónì,Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.