Àìsáyà 35:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+ Ìfihàn 7:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 torí Ọ̀dọ́ Àgùntàn,+ tó wà ní àárín ìtẹ́ náà, máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn,+ ó sì máa darí wọn lọ sí àwọn ìsun* omi ìyè.+ Ọlọ́run sì máa nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn.”+ Ìfihàn 21:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó máa nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn,+ ikú ò ní sí mọ́,+ kò ní sí ọ̀fọ̀ tàbí ẹkún tàbí ìrora mọ́.+ Àwọn nǹkan àtijọ́ ti kọjá lọ.”
10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+
17 torí Ọ̀dọ́ Àgùntàn,+ tó wà ní àárín ìtẹ́ náà, máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn,+ ó sì máa darí wọn lọ sí àwọn ìsun* omi ìyè.+ Ọlọ́run sì máa nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn.”+
4 Ó máa nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn,+ ikú ò ní sí mọ́,+ kò ní sí ọ̀fọ̀ tàbí ẹkún tàbí ìrora mọ́.+ Àwọn nǹkan àtijọ́ ti kọjá lọ.”