Sáàmù 34:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ tọ́ ọ wò, kí ẹ sì rí i pé ẹni rere ni Jèhófà,+Aláyọ̀ ni ọkùnrin tí ó fi í ṣe ibi ààbò. Sáàmù 146:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Aláyọ̀ ni ẹni tí Ọlọ́run Jékọ́bù jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,+Tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,+ Àìsáyà 26:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+
5 Aláyọ̀ ni ẹni tí Ọlọ́run Jékọ́bù jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,+Tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,+ Àìsáyà 26:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+
3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+