-
2 Kíróníkà 12:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tí Jèhófà rí i pé wọ́n ti rẹ ara wọn sílẹ̀, Jèhófà bá Ṣemáyà sọ̀rọ̀, ó ní: “Wọ́n ti rẹ ara wọn sílẹ̀. Mi ò ní pa wọ́n run,+ màá sì gbà wọ́n láìpẹ́. Mi ò ní tú ìbínú mi sórí Jerúsálẹ́mù látọwọ́ Ṣíṣákì. 8 Ṣùgbọ́n wọ́n á di ìránṣẹ́ rẹ̀, kí wọ́n lè mọ ìyàtọ̀ nínú sísìn mí àti sísin àwọn ọba* ilẹ̀ míì.”
-