2 Àwọn Ọba 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+ Àìsáyà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọ̀nà kan sì máa jáde+ láti Ásíríà fún àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ yòókù,+Bó ṣe rí fún Ísírẹ́lì ní ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì. Hósíà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọn kò ní gbé ilẹ̀ Jèhófà mọ́;+Kàkà bẹ́ẹ̀, Éfúrémù á pa dà sí Íjíbítì,Wọ́n á sì jẹ ohun àìmọ́ ní Ásíríà.+
6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+
16 Ọ̀nà kan sì máa jáde+ láti Ásíríà fún àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ yòókù,+Bó ṣe rí fún Ísírẹ́lì ní ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
3 Wọn kò ní gbé ilẹ̀ Jèhófà mọ́;+Kàkà bẹ́ẹ̀, Éfúrémù á pa dà sí Íjíbítì,Wọ́n á sì jẹ ohun àìmọ́ ní Ásíríà.+