2 Àwọn Ọba 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+ Àìsáyà 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ìlú olódi ò ní sí mọ́ ní Éfúrémù,+Ìjọba ò sì ní sí mọ́ ní Damásíkù;+Àwọn tó ṣẹ́ kù lára SíríàSì máa dà bí ògo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,”* ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+
3 Àwọn ìlú olódi ò ní sí mọ́ ní Éfúrémù,+Ìjọba ò sì ní sí mọ́ ní Damásíkù;+Àwọn tó ṣẹ́ kù lára SíríàSì máa dà bí ògo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,”* ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.