- 
	                        
            
            Jeremáyà 5:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        15 “Wò ó, màá mú orílẹ̀-èdè kan láti ibi tó jìnnà wá bá yín, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì,”+ ni Jèhófà wí. “Orílẹ̀-èdè tó ti wà tipẹ́tipẹ́ ni. 
 
-