- 
	                        
            
            Jeremáyà 4:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        16 Ẹ ròyìn rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni, ẹ ròyìn rẹ̀ fún àwọn orílẹ̀-èdè; Ẹ kéde rẹ̀ sórí Jerúsálẹ́mù.” “Àwọn ẹ̀ṣọ́* ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà, Wọ́n á sì gbé ohùn wọn sókè sí àwọn ìlú Júdà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 25:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Màá ránṣẹ́ pe gbogbo ìdílé tó wà ní àríwá,”+ ni Jèhófà wí, “màá ránṣẹ́ sí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì, ìránṣẹ́ mi,+ màá mú wọn wá láti gbéjà ko ilẹ̀ yìí+ àti àwọn tó ń gbé lórí rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo orílẹ̀-èdè tó yí i ká.+ Màá pa wọ́n run pátápátá, màá sì sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù àti ohun àrísúfèé àti ibi àwókù títí láé. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Hábákúkù 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Wọ́n yára bolẹ̀ káàkiri ayé Láti gba àwọn ilé tí kì í ṣe tiwọn.+ 
 
-