Àìsáyà 41:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Wò ó! Mo ti sọ ọ́ di ohun tí wọ́n fi ń pakà,+Ohun tuntun tó ní eyín olójú méjì tí wọ́n fi ń pakà. O máa tẹ àwọn òkè ńlá mọ́lẹ̀, o máa fọ́ wọn túútúú,O sì máa ṣe àwọn òkè kéékèèké bí ìyàngbò.* Émọ́sì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Damásíkù àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n fi ohun èlò ìpakà onírin pa Gílíádì bí ọkà.+
15 “Wò ó! Mo ti sọ ọ́ di ohun tí wọ́n fi ń pakà,+Ohun tuntun tó ní eyín olójú méjì tí wọ́n fi ń pakà. O máa tẹ àwọn òkè ńlá mọ́lẹ̀, o máa fọ́ wọn túútúú,O sì máa ṣe àwọn òkè kéékèèké bí ìyàngbò.*
3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘“Nítorí ìdìtẹ̀* mẹ́ta Damásíkù àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n fi ohun èlò ìpakà onírin pa Gílíádì bí ọkà.+