Àìsáyà 51:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ohun méjì yìí ti dé bá ọ. Ta ló máa bá ọ kẹ́dùn? Ìparun àti ìsọdahoro, ebi àti idà!+ Ta ló máa tù ọ́ nínú?+ Ìdárò 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá.
19 Ohun méjì yìí ti dé bá ọ. Ta ló máa bá ọ kẹ́dùn? Ìparun àti ìsọdahoro, ebi àti idà!+ Ta ló máa tù ọ́ nínú?+
4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá.