Àìsáyà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+Torí Jèhófà ti sọ pé: “Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà, Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+ Àìsáyà 63:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+ Àìsáyà 65:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo ti tẹ́ ọwọ́ mi sí àwọn alágídí láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+Sí àwọn tó ń rìn ní ọ̀nà tí kò dáa,+Tí wọ́n ń tẹ̀ lé èrò tiwọn;+
2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+Torí Jèhófà ti sọ pé: “Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà, Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+
10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+
2 Mo ti tẹ́ ọwọ́ mi sí àwọn alágídí láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+Sí àwọn tó ń rìn ní ọ̀nà tí kò dáa,+Tí wọ́n ń tẹ̀ lé èrò tiwọn;+