Jóẹ́lì 2:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ẹ ó sì mọ̀ pé mo wà láàárín Ísírẹ́lì+Àti pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kò sí ẹlòmíì! Wọn ò ní dójú ti àwọn èèyàn mi mọ́ láé.
27 Ẹ ó sì mọ̀ pé mo wà láàárín Ísírẹ́lì+Àti pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kò sí ẹlòmíì! Wọn ò ní dójú ti àwọn èèyàn mi mọ́ láé.