Diutarónómì 31:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́! Àìsáyà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́! Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i. Jeremáyà 44:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìdí ni pé wọ́n hùwà ibi láti mú mi bínú, torí wọ́n lọ ń rú ẹbọ,+ wọ́n sì ń sin àwọn ọlọ́run míì tí wọn kò mọ̀, tí ẹ̀yin tàbí àwọn baba ńlá yín náà kò sì mọ̀.+
27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́!
4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́! Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i.
3 Ìdí ni pé wọ́n hùwà ibi láti mú mi bínú, torí wọ́n lọ ń rú ẹbọ,+ wọ́n sì ń sin àwọn ọlọ́run míì tí wọn kò mọ̀, tí ẹ̀yin tàbí àwọn baba ńlá yín náà kò sì mọ̀.+