ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 59:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Torí ẹ̀jẹ̀ ti sọ àtẹ́lẹwọ́ yín di eléèérí,+

      Ẹ̀ṣẹ̀ sì ti sọ ìka yín di eléèérí.

      Ètè yín ń parọ́,+ ahọ́n yín sì ń sọ àìṣòdodo kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́.

  • Jeremáyà 9:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Wọ́n tẹ ahọ́n wọn bí ọrun;

      Èké ṣíṣe ló gba ilẹ̀ náà kan, kì í ṣe òtítọ́.+

      “Wọ́n ń tinú ibi bọ́ sínú ibi,

      Wọn ò sì kà mí sí,”+ ni Jèhófà wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́