6 Jèhófà ń kọjá níwájú rẹ̀, ó sì ń kéde pé: “Jèhófà, Jèhófà, Ọlọ́run aláàánú,+ tó ń gba tẹni rò,*+ tí kì í tètè bínú,+ tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀*+ àti òtítọ́*+ rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi,
9 Torí mo wà pẹ̀lú yín, èmi yóò sì yíjú sí yín. Wọ́n á fi yín dáko, wọ́n á sì fún irúgbìn sínú yín. 10 Màá mú kí àwọn èèyàn rẹ pọ̀ sí i, gbogbo ilé Ísírẹ́lì, gbogbo rẹ̀ pátá, wọ́n á máa gbé inú àwọn ìlú náà,+ wọ́n á sì tún àwọn àwókù náà kọ́.+