Jeremáyà 29:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘Nítorí mo mọ èrò tí mò ń rò nípa yín dáadáa,’ ni Jèhófà wí, ‘èrò àlàáfíà, kì í ṣe ti àjálù,+ láti fún yín ní ọjọ́ ọ̀la kan àti ìrètí kan.+ 12 Ẹ ó pè mí, ẹ ó sì wá gbàdúrà sí mi, màá sì fetí sí yín.’+
11 “‘Nítorí mo mọ èrò tí mò ń rò nípa yín dáadáa,’ ni Jèhófà wí, ‘èrò àlàáfíà, kì í ṣe ti àjálù,+ láti fún yín ní ọjọ́ ọ̀la kan àti ìrètí kan.+ 12 Ẹ ó pè mí, ẹ ó sì wá gbàdúrà sí mi, màá sì fetí sí yín.’+