-
Nọ́ńbà 20:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Jọ̀ọ́, jẹ́ ká gba ilẹ̀ rẹ kọjá. A ò ní gba inú oko kankan tàbí ọgbà àjàrà, a ò sì ní mu omi kànga kankan. Ojú Ọ̀nà Ọba la máa gbà, a ò ní yà sí ọ̀tún tàbí sí òsì títí a fi máa kọjá ní ilẹ̀+ rẹ.’”
-