10 Ó tún sọ Tófétì+ tó wà ní Àfonífojì Àwọn Ọmọ Hínómù*+ di ibi tí kò ṣeé lò fún ìjọsìn, kí ẹnikẹ́ni má bàa sun ọmọkùnrin rẹ̀ tàbí ọmọbìnrin rẹ̀ nínú iná sí Mólékì.+
32 “‘Nítorí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí, ‘tí a kò ní pè é ní Tófétì tàbí Àfonífojì Ọmọ Hínómù mọ́,* àmọ́ Àfonífojì Ìpànìyàn la ó máa pè é. Wọ́n á sin òkú ní Tófétì títí kò fi ní sí àyè mọ́.+