Diutarónómì 32:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Bí ẹyẹ idì ṣe ń ru ìtẹ́ rẹ̀ sókè,Tó ń rá bàbà lórí àwọn ọmọ rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gúnyẹ̀ẹ́,Tó ń na àwọn ìyẹ́ rẹ̀ jáde láti fi gbé wọn,Tó ń gbé wọn sórí apá+ rẹ̀, 12 Jèhófà nìkan ló ń darí rẹ̀;*+Kò sí ọlọ́run àjèjì kankan pẹ̀lú rẹ̀.+ Sáàmù 91:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.
11 Bí ẹyẹ idì ṣe ń ru ìtẹ́ rẹ̀ sókè,Tó ń rá bàbà lórí àwọn ọmọ rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gúnyẹ̀ẹ́,Tó ń na àwọn ìyẹ́ rẹ̀ jáde láti fi gbé wọn,Tó ń gbé wọn sórí apá+ rẹ̀, 12 Jèhófà nìkan ló ń darí rẹ̀;*+Kò sí ọlọ́run àjèjì kankan pẹ̀lú rẹ̀.+
4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.