Àìsáyà 27:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí wọ́n máa pa ìlú olódi tì;Wọ́n máa pa àwọn ibi ìjẹko tì, wọ́n á sì fi í sílẹ̀ bí aginjù.+ Ibẹ̀ ni ọmọ màlúù á ti máa jẹko, tó sì máa dùbúlẹ̀ sí,Ó sì máa jẹ àwọn ẹ̀ka rẹ̀.+
10 Torí wọ́n máa pa ìlú olódi tì;Wọ́n máa pa àwọn ibi ìjẹko tì, wọ́n á sì fi í sílẹ̀ bí aginjù.+ Ibẹ̀ ni ọmọ màlúù á ti máa jẹko, tó sì máa dùbúlẹ̀ sí,Ó sì máa jẹ àwọn ẹ̀ka rẹ̀.+