Sáàmù 46:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ẹ túúbá, kí ẹ sì mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run. A ó gbé mi ga láàárín àwọn orílẹ̀-èdè;+A ó gbé mi ga ní ayé.”+
10 “Ẹ túúbá, kí ẹ sì mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run. A ó gbé mi ga láàárín àwọn orílẹ̀-èdè;+A ó gbé mi ga ní ayé.”+