Diutarónómì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè. Náhúmù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀. Hébérù 12:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí Ọlọ́run wa jẹ́ iná tó ń jóni run.+
22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.
6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.