Ẹ́kísódù 23:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí àwọn tó ríran kedere lójú, ó sì lè mú kí àwọn olódodo yí ọ̀rọ̀ po.+ Diutarónómì 16:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 O ò gbọ́dọ̀ ṣe èrú tí o bá ń dájọ́,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣe ojúsàájú,+ o ò sì gbọ́dọ̀ gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí ọlọ́gbọ́n lójú,+ ó sì máa ń mú kí olódodo yí ọ̀rọ̀ po.
8 “Má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí àwọn tó ríran kedere lójú, ó sì lè mú kí àwọn olódodo yí ọ̀rọ̀ po.+
19 O ò gbọ́dọ̀ ṣe èrú tí o bá ń dájọ́,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣe ojúsàájú,+ o ò sì gbọ́dọ̀ gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí ọlọ́gbọ́n lójú,+ ó sì máa ń mú kí olódodo yí ọ̀rọ̀ po.