ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 23:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 “Má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí àwọn tó ríran kedere lójú, ó sì lè mú kí àwọn olódodo yí ọ̀rọ̀ po.+

  • 1 Sámúẹ́lì 12:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Èmi nìyí. Ẹ ta kò mí níwájú Jèhófà àti níwájú ẹni àmì òróró rẹ̀:+ Akọ màlúù tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ta ni mo gbà rí?+ Àbí, ta ni mo lù ní jìbìtì tàbí tí mo ni lára? Ọwọ́ ta ni mo ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,* tí màá fi gbé ojú mi sẹ́gbẹ̀ẹ́?+ Tó bá wà, màá san án pa dà fún yín.”+

  • Oníwàásù 7:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ìnilára lè mú kí ọlọ́gbọ́n ṣe bíi wèrè, àbẹ̀tẹ́lẹ̀ sì ń sọ ọkàn dìdàkudà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́