Àìsáyà 27:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí náà, báyìí la ṣe máa ṣètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ Jékọ́bù,+Èyí sì ni ohun tó máa jèrè lẹ́kùn-ún rẹ́rẹ́ nígbà tí a bá mú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kúrò: Ó máa ṣe gbogbo òkúta pẹpẹ Bí òkúta ẹfun tí wọ́n lọ̀ lúúlúú,Òpó òrìṣà* àti pẹpẹ tùràrí kankan ò sì ní ṣẹ́ kù.+
9 Torí náà, báyìí la ṣe máa ṣètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ Jékọ́bù,+Èyí sì ni ohun tó máa jèrè lẹ́kùn-ún rẹ́rẹ́ nígbà tí a bá mú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kúrò: Ó máa ṣe gbogbo òkúta pẹpẹ Bí òkúta ẹfun tí wọ́n lọ̀ lúúlúú,Òpó òrìṣà* àti pẹpẹ tùràrí kankan ò sì ní ṣẹ́ kù.+