-
Àìsáyà 31:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Torí pé ní ọjọ́ yẹn, kálukú máa kọ àwọn ọlọ́run rẹ̀ tí kò ní láárí, tó fi fàdákà ṣe àti àwọn ọlọ́run rẹ̀ tí kò wúlò, tó fi wúrà ṣe, èyí tí ẹ fi ọwọ́ ara yín ṣe, tó sì jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.
-