-
2 Àwọn Ọba 19:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti pinnu rẹ̀.*+
Láti ọ̀pọ̀ ọjọ́ sẹ́yìn ni mo ti ṣètò* rẹ̀.+
Ní báyìí, màá ṣe é.+
Wàá sọ àwọn ìlú olódi di àwókù.+
26 Àwọn tó ń gbé inú wọn á di aláìlágbára;
Jìnnìjìnnì á bá wọn, ojú á sì tì wọ́n.
Wọ́n á rọ bí ewéko pápá àti bí koríko tútù ṣe máa ń rọ,+
Bíi koríko orí òrùlé tí atẹ́gùn ìlà oòrùn ti jó gbẹ.
-