Òwe 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí àwọn ọ̀nà èèyàn wà níwájú Jèhófà;Ó ń ṣàyẹ̀wò gbogbo ipa ọ̀nà rẹ̀.+ Òwe 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ojú Jèhófà wà níbi gbogbo,Ó ń ṣọ́ ẹni burúkú àti ẹni rere.+ Hébérù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+
13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+