Jẹ́nẹ́sísì 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ pé: “Igbe àwọn tó ń ráhùn nípa Sódómù àti Gòmórà ti pọ̀ gidigidi,+ ẹ̀ṣẹ̀ wọn sì wúwo gan-an.+ Àìsáyà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹ̀yin apàṣẹwàá* Sódómù.+ Ẹ fetí sí òfin* Ọlọ́run wa, ẹ̀yin èèyàn Gòmórà.+ Júùdù 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lọ́nà kan náà, Sódómù àti Gòmórà àti àwọn ìlú tó yí wọn ká ṣe ìṣekúṣe* tó burú jáì, wọ́n ṣe ìfẹ́ tara tí kò bá ìwà ẹ̀dá mu.+ Ìdájọ́ ìparun* ayérayé tí wọ́n gbà jẹ́ àpẹẹrẹ láti kìlọ̀ fún wa.+
20 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ pé: “Igbe àwọn tó ń ráhùn nípa Sódómù àti Gòmórà ti pọ̀ gidigidi,+ ẹ̀ṣẹ̀ wọn sì wúwo gan-an.+
7 Lọ́nà kan náà, Sódómù àti Gòmórà àti àwọn ìlú tó yí wọn ká ṣe ìṣekúṣe* tó burú jáì, wọ́n ṣe ìfẹ́ tara tí kò bá ìwà ẹ̀dá mu.+ Ìdájọ́ ìparun* ayérayé tí wọ́n gbà jẹ́ àpẹẹrẹ láti kìlọ̀ fún wa.+