Àìsáyà 42:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá mú àwọn afọ́jú gba ọ̀nà tí wọn ò mọ̀,+Màá sì mú kí wọ́n gba ọ̀nà tó ṣàjèjì sí wọn.+ Màá sọ òkùnkùn tó wà níwájú wọn di ìmọ́lẹ̀,+Màá sì sọ ilẹ̀ tó rí gbágungbàgun di ilẹ̀ tó tẹ́jú.+ Ohun tí màá ṣe fún wọn nìyí, mi ò sì ní fi wọ́n sílẹ̀.”
16 Màá mú àwọn afọ́jú gba ọ̀nà tí wọn ò mọ̀,+Màá sì mú kí wọ́n gba ọ̀nà tó ṣàjèjì sí wọn.+ Màá sọ òkùnkùn tó wà níwájú wọn di ìmọ́lẹ̀,+Màá sì sọ ilẹ̀ tó rí gbágungbàgun di ilẹ̀ tó tẹ́jú.+ Ohun tí màá ṣe fún wọn nìyí, mi ò sì ní fi wọ́n sílẹ̀.”