Àìsáyà 29:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn adití máa gbọ́ ọ̀rọ̀ inú ìwé náà,Àwọn afọ́jú sì máa ríran látinú ìṣúdùdù àti òkùnkùn.+ Àìsáyà 35:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yẹn, ojú àwọn afọ́jú máa là,+Etí àwọn adití sì máa ṣí.+ Jeremáyà 31:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá mú wọn pa dà wá láti ilẹ̀ àríwá.+ Màá sì kó wọn jọ láti ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+ Àwọn afọ́jú àti àwọn arọ máa wà lára wọn,+Aboyún àti ẹni tó ń rọbí, gbogbo wọn pa pọ̀. Bí ìjọ ńlá ni wọ́n máa pa dà sí ibí yìí.+
18 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn adití máa gbọ́ ọ̀rọ̀ inú ìwé náà,Àwọn afọ́jú sì máa ríran látinú ìṣúdùdù àti òkùnkùn.+
8 Màá mú wọn pa dà wá láti ilẹ̀ àríwá.+ Màá sì kó wọn jọ láti ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+ Àwọn afọ́jú àti àwọn arọ máa wà lára wọn,+Aboyún àti ẹni tó ń rọbí, gbogbo wọn pa pọ̀. Bí ìjọ ńlá ni wọ́n máa pa dà sí ibí yìí.+