Jóòbù 14:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+ Sáàmù 90:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O gbá wọn lọ;+ wọ́n dà bí oorun lásán;Ní àárọ̀, wọ́n dà bíi koríko tó yọ.+ 6 Ní àárọ̀, ó yọ ìtànná, ó sì dọ̀tun,Àmọ́ ní ìrọ̀lẹ́, ó rọ, ó sì gbẹ dà nù.+
14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+
5 O gbá wọn lọ;+ wọ́n dà bí oorun lásán;Ní àárọ̀, wọ́n dà bíi koríko tó yọ.+ 6 Ní àárọ̀, ó yọ ìtànná, ó sì dọ̀tun,Àmọ́ ní ìrọ̀lẹ́, ó rọ, ó sì gbẹ dà nù.+