Àìsáyà 46:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Láti ìbẹ̀rẹ̀, mò ń sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀,Tipẹ́tipẹ́ ni mo sì ti ń sọ àwọn ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀.+ Mo sọ pé, ‘Ìpinnu mi* máa dúró,+Màá sì ṣe ohunkóhun tó bá wù mí.’+ 1 Pétérù 1:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí “gbogbo ẹran ara* dà bíi koríko, gbogbo ògo rẹ̀ sì dà bí ìtànná àwọn ewéko; koríko máa ń gbẹ, òdòdó sì máa ń rẹ̀ dà nù, 25 àmọ́ ọ̀rọ̀* Jèhófà* wà títí láé.”+ “Ọ̀rọ̀”* yìí ni ìhìn rere tí a kéde rẹ̀ fún yín.+
10 Láti ìbẹ̀rẹ̀, mò ń sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀,Tipẹ́tipẹ́ ni mo sì ti ń sọ àwọn ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀.+ Mo sọ pé, ‘Ìpinnu mi* máa dúró,+Màá sì ṣe ohunkóhun tó bá wù mí.’+
24 Torí “gbogbo ẹran ara* dà bíi koríko, gbogbo ògo rẹ̀ sì dà bí ìtànná àwọn ewéko; koríko máa ń gbẹ, òdòdó sì máa ń rẹ̀ dà nù, 25 àmọ́ ọ̀rọ̀* Jèhófà* wà títí láé.”+ “Ọ̀rọ̀”* yìí ni ìhìn rere tí a kéde rẹ̀ fún yín.+