- 
	                        
            
            Àìsáyà 45:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        21 Ẹ sọ tẹnu yín, ẹ ro ẹjọ́ yín. Kí wọ́n fikùn lukùn ní ìṣọ̀kan. Ta ló ti sọ èyí tipẹ́tipẹ́, Tó sì kéde rẹ̀ láti ìgbà àtijọ́? Ṣebí èmi, Jèhófà ni? 
 
-