Òwe 30:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ta ló ti gòkè lọ sí ọ̀run tó sì sọ̀ kalẹ̀ wá?+ Ta ló ti kó ẹ̀fúùfù jọ sí àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ méjèèjì? Ta ló ti di omi sínú aṣọ rẹ̀?+ Ta ló ti fi ìdí gbogbo ìkángun ayé sọlẹ̀?*+ Kí ni orúkọ rẹ̀, kí sì ni orúkọ ọmọ rẹ̀, tí o bá mọ̀ ọ́n?
4 Ta ló ti gòkè lọ sí ọ̀run tó sì sọ̀ kalẹ̀ wá?+ Ta ló ti kó ẹ̀fúùfù jọ sí àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ méjèèjì? Ta ló ti di omi sínú aṣọ rẹ̀?+ Ta ló ti fi ìdí gbogbo ìkángun ayé sọlẹ̀?*+ Kí ni orúkọ rẹ̀, kí sì ni orúkọ ọmọ rẹ̀, tí o bá mọ̀ ọ́n?