Jóòbù 38:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ibo lo wà nígbà tí mo fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀?+ Sọ fún mi, tí o bá rò pé o mọ̀ ọ́n. 5 Ta ló díwọ̀n rẹ̀, tí o bá mọ̀ ọ́n,Àbí ta ló na okùn ìdíwọ̀n sórí rẹ̀?
4 Ibo lo wà nígbà tí mo fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀?+ Sọ fún mi, tí o bá rò pé o mọ̀ ọ́n. 5 Ta ló díwọ̀n rẹ̀, tí o bá mọ̀ ọ́n,Àbí ta ló na okùn ìdíwọ̀n sórí rẹ̀?