-
Sáàmù 136:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ó tẹ́ ayé sórí omi,+
Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.
-
-
Òwe 8:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Nígbà tó pàṣẹ fún òkun
Pé kí omi rẹ̀ má kọjá àṣẹ tó pa fún un,+
Nígbà tó fi àwọn ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,*
-
Hébérù 1:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àti pé: “Ní ìbẹ̀rẹ̀, Olúwa, o fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀, ọ̀run sì jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.
-
-
-