Rúùtù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Bóásì wá sọ fún àwọn àgbààgbà àti gbogbo èèyàn náà pé: “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí+ mi lónìí pé mò ń ra gbogbo ohun tó jẹ́ ti Élímélékì àti gbogbo ohun tó jẹ́ ti Kílíónì àti Málónì lọ́wọ́ Náómì.
9 Bóásì wá sọ fún àwọn àgbààgbà àti gbogbo èèyàn náà pé: “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí+ mi lónìí pé mò ń ra gbogbo ohun tó jẹ́ ti Élímélékì àti gbogbo ohun tó jẹ́ ti Kílíónì àti Málónì lọ́wọ́ Náómì.