ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 23:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 ohun ìní Ábúráhámù, èyí tó rà níṣojú àwọn ọmọ Hétì àti gbogbo àwọn tó ń gba ẹnubodè ìlú rẹ̀ wọlé.

  • Rúùtù 4:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Torí náà, mo rò pé ó yẹ kí n sọ fún ọ nípa rẹ̀ pé, ‘Rà á níṣojú àwọn ará ìlú àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn mi.+ Tí o bá máa tún un rà, tún un rà. Ṣùgbọ́n tí o kò bá ní tún un rà, jọ̀ọ́ sọ fún mi, kí n lè mọ̀, torí ìwọ lo lẹ́tọ̀ọ́ láti tún un rà, èmi ló sì tẹ̀ lé ọ.’” Ó dáhùn pé: “Màá tún un rà.”+

  • Jeremáyà 32:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 mo sì fún Bárúkù,+ ọmọ Neráyà,+ ọmọ Maseáyà ní ìwé àdéhùn náà lójú Hánámélì ọmọ arákùnrin bàbá mi àti lójú àwọn ẹlẹ́rìí tó buwọ́ lu ìwé àdéhùn náà àti lójú gbogbo àwọn Júù tó jókòó sí Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́